The Foundation on the Rock

Ẹkaabo si iṣẹ-iranṣẹ wa​

Ẹkaabo si iṣẹ-iranṣẹ wa

Isẹ wa

Alakoso Ipilẹ wa

orí àpáta yìí ni èmi yóò kọ́ ìjọ mi lé, àti ẹnu-ọ̀nà ipò òkú kì yóò lè borí rẹ̀. (Matiu 16: 18)

Eto osoosu fun ijo wa ati ori oke

HTML Calendar

Every month

1 – 3

Headquarter Amunkoko Lagos

Every month

13 – 15

Sabo Elegbo Sangote Area Oyo

Every month

15 – 17

Ilogbo Branch, Ogun State

Every month

18 – 20

Oja Agbe Maternity Centre Koso Iseyin

Every month

20 – 22

Konifewo Branch Ogun State

Every month

26 – 28

Ori Oke Jesu Ghogunmi Iseyin Oyo State

Itan ti oludasilẹ wa​

Adelowo Olusoa Adediran

Adelowo Olusoa Adediran​

Mojẹ ọmọ bibi  ilu Ọyọ Ni ago  agbo ile OJoyage. Olusoagutan Olusola Adelowo je enikan ti o ri oju rere Olorun gba pupo. Ni ibẹrẹ igbesi aye mi Mo jẹ ẹnikan ti o jẹ alagidi pupọ, jagunjagun, pẹlu aiṣedeede iwa. Modupẹ lọwọ olorun pe  unko wọ Ẹgbẹ Ajẹ tabi Ẹgbẹ Ole tabi ẹgbẹ okunkun Kankan. Sungbọn mojẹ ẹniken ti ko letosi ohun ti Jesu Kristi  fi mi pe rara. Ni ti ile-iwe, ko si oore-ọfẹ fun mi lati lọ si ile-iwe ti o dara ati kọja kilasi karun.

Lati igba ti mo ti kuro ni ile ẹkọ alakọbẹrẹ ni oko kan ti ape ni oja koso. mo bẹrẹ   si ni se ọmọ  ẹyin ọkọ kakiri kin to pade okunrin kan ti a pe orukorẹ ni “Asani ; ẹni to o ko mi bi ati sema mu igbo. Ti osi bẹrẹ si ma fun mi ni orisirisi ogun ti o ni agbara. Awan ikan wonyi ni ko jẹki ọrọ aye mi ti lẹ ni oju rara. Ka ma fa ọrọgun, momon.” motor (ọkọ) wa. Ti baba mi si gba iwe ẹri iwakọ fun mi. Lẹyin naa ni mo lọ si ilu Abuja lati lowa ọkọ fun at jenu.  

Laie fa ọrọ gun, mo pa da wa sile ni ilu Ọyọ ni ọdun 2002 ti mo situn wa wo ise arobo/Trader. Ni gba ti mo pari  Lẹyin ọdun kan,  mo pada si ilu Abuja ni ọdun 2003. Lati wa owo isẹ lọ. Lẹ nu rẹẹn ni mo bẹẹrẹ situn wa motor ti mo fi pade pastor  ti oruko re je Gbeunga Ọdẹtola ti mo bẹẹrẹ si sun mon won. Ẹni yi ni kan ni mo gbo lati ẹnu re pe mo ni ipe olusọ aguntan, Sugbon ko ye mi.

Sugbon ọjọ  kan ti emi ko le gbagbe ni ọjọ ti mo gbọ ohun  Oluwa Olorun si eti mi 3-3- 2004 ti iderun si ba mi  so ọrọ gẹgẹ bi baba si ọmọ. Ẹru ba mi gidi gidi. Lati ọjọ yi ni gbogbo ọnan ti mo ba dawọsi ti bẹrẹ si jasi pabo. Eyi lo mumi lati joko si ori oke fun osu meta ati ọjọ die  kin to pada si ile lati  lo bẹrẹ isẹ oluwa ninu ijọ kan ni ilu Ọyọ ti a pe oruko re ni Christ Power Evangelist Church. Leyin odun diẹ Ọlọrun tun mumi tẹsiwaju losi ijo miran ti a pe ni GRACE & GLORY BIBLE CHURCH ni ilu Ọyọ.  Ti mo si tun lo awon akoko kan ni bẹ. Lẹyin nan Ọlọrun mun mi lo silu EKo  ti mosi tun sisẹ ninu awon ijọ miran.  Ki Olorun to pasẹ fun mi  lati da ijọ tiwa na silẹ ni ọjọ kẹta, osu karun ọdun 2006. (03-05-2006)